Ìdájọ́ ikú ló yẹ fún àwọn tó ń ju àdó-olóró kiri – Trump
Aare orileede Amerika, Donald Trump ni o n salaye yii ni owuro oni ni igba ti owo te Akayed Ulla ti ojo ori re ko ju odun metadinlogbon lo. O tun je omo orileede Bangladeshi to n wa oko tasi ni orileede Amerika.
Ado-oloro yii se awon eniyan meta lese yanna-yanna.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…