Home iroyin Onídájọ́ Ademọla Adeniyi fiṣẹ́ sílẹ̀ lójijì
iroyin - December 7, 2017

Onídájọ́ Ademọla Adeniyi fiṣẹ́ sílẹ̀ lójijì

Onidajo ile-ejo giga agba ni olu-ilu Naijiria l’Abuja ni o dede kowe fise sile ni ojo kefa, osu kokanla odun yii. Osu keta odun to n bo lo ye ki ojo ifeyinti re pe.
Ti ko ba nidii, obinrin kii je kumolu. Idi ti onidajo yii se fi ise sile ni osan kan, oru kan ko ye enikankan titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọlọ́ọ̀pá ATRS yòó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó dípò SARS

Ọlọ́ọ̀pá ATRS yòó yòó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó dípò SARS Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ètò ààbò ìl…