Home iroyin Ẹ̀rù ń ba ọmọ Naijiria lórí epo Pẹtiró
iroyin - December 5, 2017

Ẹ̀rù ń ba ọmọ Naijiria lórí epo Pẹtiró

Oro epo prtiro ma ti di oro ti “a n pe ti o n laro ninu”. Awon omo Naijiria wuu gbo pe ijoba apapo fe fi kun owo epo ni ose to oja, ijoba apapo si ni ko si ohun to joo. Ijoba tile ni ki awon ara ilu ma se da awon alaheso lohun, nitori pe epo to wa lowo bayii ko le tan kiakia.
Lonii, oro naa ti koja “won ni, won pe”. Awon onimoto, olokada pelu awon oni keegi maa tun ti to lo tuurutu fun epo ti ijoba ni ko ni won.
Gege bi iroyin to te wa lowo bayii, won ni epo petiro ti di naira marundinloodunrun (N250) fun jala epo kan, nigba ti awon ipinle miran n taa ni igba naira ati bee bee lo.
Awon ajo elepo meji lo n ti oro naa si ara won bayii, awon ajo IPMAN ni awon NNPC ni ko gbepo to nigba ti awon NNPC ni awon ni ile-epo ti awon, ti ko si eyi to kan awon pelu awon ile epo ti o ku.
Gbogbo awon ilu nla-nla ni orileede yii ni won ti bere sin i to fun epo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin Ọrẹ Òtítọ́jù Iná ọkọ,aya …