Yakubu the Yak, o dabo
Yakubu the Yak, o dabo
Asiko niyi lati ki Yakubu Aiyegbeni pe o dabo o. Ti iku ko, ti arun ko, Yakubu Aiygbeni feyinti ninu boolu gbigba ni.
Bi o tile je pe goolu nla to miisi ninu idije Super Eagles ati South Korea lasiko World Cup ni opo eniyan n ranti ni, e mu u, e ki i eranko bee ko ni oore.
Bi a fe bi a ko, Yakubu kii se egbe agbaboolu Naijiria yoku ninu iye goolu to gba wole ni Premier League. Koda, o s’agba Kanu ati Moses gan-an, tori goolu marundinlogorun (95 goals) ni ogba wole ni Premier League.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…