Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ogbeni Moyes, ewo le tun fe se ni West Ham o?
ERÉ ÌDÁRAYÁ - November 29, 2017

Ogbeni Moyes, ewo le tun fe se ni West Ham o?

 

To ba je pe omo Aafirika, paapaa omo Yoruba, ni adari agbaboolu Premier League, David Moyes, ni, awon eniyan kiba ti maa gba a nimoran pe ki o o we ori re lodo Osun.

Won ba ni ko gbe ori re fun alayewo, latari amubo ti o n mou lojoojumo nibi to ba ti sise.

Eyi lo se ya opo lenu pe oun ni Ifa West Ham tun mu nigba ti won n wa koosi ti yoo mu won jade ninu ogbon relegation zone ti won wa.

Bi o tile je pe Moyes se daadaa die ni Everton, won gba a nipako jade ni Man U, Real Sociedad ati Sunderland ni, ngba ti o fe ko okuta ba won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…