Aikawe ni ko je ki n ti ju bayii lo – Baba Latin
Alawada kerikeri, Bolaji Amusan, ti so pataki ipa ti eko akadunju n ko ninu idagbasoke omo eniyan.
Osere naa ti opo eniyan mo si Baba Latin so pe aikaweto oun ni ko je ki oun ti moke ju bi oun se wa lo.
O ni ti eniyan ba gboju le ere sise tabi orin kiko ni Yoruba nikan, o nibi ti agbega re maa mo.
O se arokan yii ninu iforowero kan, nibi to ti so pe oun ti bere sii ko eko atigba oye first degree, ni National Open University.
Latin ni awon akegbe oun to n se fiimu oloyinbo de, to fi mo John Okafor ti a mo si Mr. Ibu, ti moke ju awon oniYoruba lo tori opo eniyan kaakiri agbaye lo n ba won se.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…