Home Orisirisi O digba, Alex Ekwueme!
Orisirisi - November 20, 2017

O digba, Alex Ekwueme!

Igbakeji Aare oeile-ede yii tele, Oloye Alex Ekweme, ti di oloogbe bayii.

Iroyin to sese ja lule lati ilu London fi ye ni pe gbogbo ipa ti awon dokita sa lati ra emi Ekweme pada lo ja si pabo.

Naijiria ni won ti n se itoju re tele, ki won to gbe e lo si oke okun.

Ekwueme ni igbakeji Aare Sheu Shagari, ti won si jo se ijoba ni odun 1979 si 1983.

Eni odun marundin-laadorun (85 years) ni ki olojo to de.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…