Home Orisirisi Maryam pa baale re nitori ‘text message’ obinrin miran
Orisirisi - November 20, 2017

Maryam pa baale re nitori ‘text message’ obinrin miran

 

 

Nnkan buruku ti sele ninu ebi Alaga Egbe PDP tele, Alhaji Haliru Bello.

Obinrin kan, Maryam Sanda, to je iyawo omo oloselu naa, Bilyamin Bello, ti gun omokunrin naa lobe yannayanna, ti Bilyamin si gba ibe lo sorun osan gangan.

Iroyin fi to wa leti pe arabinrin naa ri leta ti ale Biliamyn ko si i gege bii text message nigba to wo foonu bale re.

Won ni ibinu ni Maryam fi wo ile lo, o lo mu obe to mu yanran-yanran, to sis a okunrin naa bi ejo aije.

A gbo pe inu bi Maryam debi pe o tun sa okunrin naa ni ada lori nnkan omokunrin re.

Digbadigba ni won ru Biliamyn lo si ile iwosan, sugbon bi won se debe ti awon dokita se ayewo re ni won ni epa ko boro mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…