Iyawo Lanre Shittu di oloogbe
Okan lara awon iyawo gbajugbaja onisowo moto, Alhaji Lanre Shittu, ti di oloogbe.
Obinrin naa ni oruko re n je Alhaja Wura Shittu, eni ti a gbo pe ilu oyinbo ni o dake si.
Iroyin fi yeni pe o ti to ojo die ti aare ti n se oloogbe naa, ki Oluwa te e si afefe rere.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…