FOR SALE! Awon PSquare fe ta ile won
Ija to wa laarin awon gbajugbaja ibeji olorin PSquare ti gba ona miran yo bayi o. Won ti fe ta gbogbo dukia ti won jo ra nigba ti nnkan n dan moran.
Bi apere, a gbo pe won ti f eta ile nla won to wa ni Omole, ni ilu Eko, eyi ti won pe ni Squareville.
Won ti gbe For Sale le ile naa lori, ti a si gbo pe N320 million ni won fe ta a
Sugbon sa o, afikun iroyin so pe Paul ati Jude ni won ni ile naa bayii. Won ni Peter ko ni nibe mo, tori Paul ati Jude ni won ni won pin in fun ni odun 2014.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…