Home Orisirisi Baba mi lo so mi ni Lai, sugbon emi kii paro –  Lai Mohammed
Orisirisi - November 9, 2017

Baba mi lo so mi ni Lai, sugbon emi kii paro –  Lai Mohammed

 

Ohun kan ti o wa loro Minisita fun Oro Iroyin ati Asa, Alhaji Lai Mohammed, ni pe bi eniyan yoo pa pelebe, yoo wi tie nu re.

O si jo pe bi oro ba ti wi lo maa n so o.

O tun ti wa salaye bayii pe opo awon to maa n pariwo ti oun ba soro, anjuwon ni oro won ti ko see wi lejo, ti ija ilara ko si tan boro.

O so fun awon oniroyin pe awon omo egbe PDP ni won maa n ta si oun ju, latari ipa ti oun ko nibi akitiyan ati gbajoba lowo won ni 2015.

O ni bi won se kuro nipo, ti APC gba ijoba dun won wonu egungun, leyii to fi je pe nigba ti ijoba Buhari de, ti oun tun je bii abenugan agba fun ijoba, ise ni won ko tun fe ri imi oun laatan.

O ni ko si oro ti oun so ti kii se otito.

Alhaji Lai Mohammed ni loooto ni baba oun so oun ni Lai, ti awon eniyan kan si n yii si ‘lie’, sugbon okodoro oro ni oun maa n so.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…