Ìwé ètò ìsúná ọdún 2018 máa tu gbogbo ayé lára – Buhari
Aare Mohammadu Buhari ti tewo gba iwe eto isuna ti odun to n bo leyin ti awon ile igbimo asofin kekere ati asoju ti yee wo finni-finni.
Aare ni idera ti de leyin opolopo ifarada omo Naijiria. Awon ile igbimo mejeeji ati Aare se eleyii lati le je ki a bere eto isuna ti odun to n bo ni ojo kinni, osu kinni odun to n bo. Won fe ki odun to n bo yato pata-pata si awon odun to ti koja ti iwe eto isuna maa n jade ni aarin odun, tabi ti awon eda kan a ti fi tiwon kun un.
Won ni eto isuna odun to n bo yato, o si maa mu idagbasoke ba orileede yii. Iye owo eto isuna naa je Tirilionu mejo le ni egbeta ati mejila naira (8.612Trn).
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…