Buhari, Atiku, Tambuwa ba Tinubu kedun lori iku omo re
Opo eniyan si n ba agba oselu, Asiwaju Bola Tinubu Kedun lori iku omokunrin re agba, Jide Tinubu, to di oloogbe lanaa.
Lara won ni Aare Muhammadu Buhari ati Alhaji Atiku Abubakar, ti won so pe adanu nla ni isele naa je.
Won ba Tinubu daro pupo, ti won si gbadura ki Olorun ba won mu owo aburu ro.
Bakan naa, Gomina Ipinle Katsina, Aminu Masari ati ti Sokoto, Tambuwa koja lo si Eko nibi ti won ti lo ba Tinubu kedun ni ile re.
Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá?
Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá? E̩ wo fídíò ìsàlè̩ yí, kí e̩ …