Home Orisirisi Paga! Tinubu padanu akobi omokunrin!
Orisirisi - November 1, 2017

Paga! Tinubu padanu akobi omokunrin!

Opo eniyan lo ti n ba Gomina Ipinle Eko tele, Asiwaju Bola Tinubu, kedun bayii, tori o padanu akobi re to je okunrin lonii.
Arakunrin naa, ti oruko re n je Jide Tinubu, je omowe pataki, to kawe gboye ni awon yunifasiti nla-nla loke okun.
Amofin Pataki naa lo tun je, to si sise pelu awon ileese nla-nla.
A ko tii mo hulehule ohun to fa iku aitojo naa, sugbon awon otookulu kaakiri Naijiria lo ti n ba Asiwaju kedun.
Lara won ni Gomina Rauf Aregbesola ti Osun.
Ki Olorun te oloogbe naa si afefe rere, ko si duro ti awon obi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá?

Òwe – O̩mo̩ gò̩, e̩ní ko má kùú, ikú kín ló máa paá? E̩ wo fídíò ìsàlè̩ yí, kí e̩ …