Home iroyin Omo ile iwe UNILORIN di eni ti won n wa
iroyin - October 30, 2017

Omo ile iwe UNILORIN di eni ti won n wa

 

Opo adura lo n lo lowo bayii pe ki Olorun dari ese omo ile iwe Yunifasiti ti Ilorin kan, Omoniyi Olumide, pada sile, o.

Lati ojo Jimoo to lo to ti jade kuro nile ni adugbo GRA, ni Ilorin, ni ko tii pada sile, ti awon ebi re ko si mo ibi to wa.

Eyi lo je ki won maa rawo ebe si gbogbo eniyan pe ti won ba ti kefin Olumide, ki won jowo je ki awon gbo lesekese.

Ori numba yii ni e le pe won si: 08053979238.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…