Àwọn adigunjalè pa Ọlọ́pàá mẹta ní Ondo
Owuro oni ni awon adigunjale ya bo ile ifowopamo kan ti o wa ni Ifon, ipinle Ondo ti won si doju ibon ko awon olopaa to n so ile-ifowo-pamo naa. Meta ninu awon olopaa yii ni o je Olorun nipe ni oju ese ti okankan ninu awon ole naa ko si ba ise naa lo.
Iwadii to gbopon ti n lo lowo bayii lati le foju awon adigunjale naa han. Oga olopaa ipinle Ondo si se ileri pe “bi aja won lo ogun odun laye, eran ogun ni”.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…