O le ni odun meji ti emi ati Rita Dominic ti soro gbeyin – Jim Iyke

Jim Iyke lo so oro yii, nigba to n se arokan lori bi oun ati Rita ti wa tele, ko to di pe ofon-on to si gbegiri, ti onikaluku wa ko eko re lowo.
O ni loooto, aarin awon dan moran tele, sugbon bi awon mejeeji se ri ojo iwaju ko ri bakan naa.
Eyi naa lo fa a ti won ko le fi fe ara won.
O ni Rita Dominic fe ki oun se awon atunto kan lori bi oun se n gbe igbe aye, sugbon eyi ko sele.
Bakan naa, Jim Iyke ni awon mejeeji sese n yo jade bi aseseyo ogomo ni nigba ti awon bere asepo, to si je pe eje omode wa lara awon.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…