Lati atimole, Kola Ogunbiyi jade lo ji moto olopaa gbe
Ti won ba n pe eniyan ni ‘Omo odaranmoran’, arakunrin kan to n je Kola Ogunbiyi ni won n ba wi.
Okunrin naa, to je omo Emure Ekiti se bebe laipe yii, nigba to lo ja moto gba lowo oga olopaa kan.
Inu atimole lo wa ni agbegbe Ogbomoso, nibi to ti n jejo oran to da tele.
Ibe lo ti rapala jade, to sit un lo digunjale ki owo palaba re to segi.
Ojo Monday ni awon olopaa Ipinle Ondo foju Kola ati awon omo karanbaani miiran han ni Akure, ti Alukoro awon Olopaa nibe, Ogbeni Femi Joseph, si so pe awon ti n wa awon odaran naa tele.
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara
Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…