Ẹni t’Ọ́lọ́run kò pa ….
Ti asiko iku ko ba tii to, iku kii pa ni. Asamọ yii lo ba arakunrin ti mọto rẹ bajẹ si oju irin reluwee ni deede asiko ti ọkọ oju irin n bo. Gbogbo ọna lo fẹrẹ di mẹ arakunrin yii, ki o to wa di wi pe ọgbọn ki o sun ijokoo rẹ sẹyin wa sii lori.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…