Home Orisirisi RONALDO da Messi mole leekan sii, o tun gba World Footballer of the Year
Orisirisi - October 23, 2017

RONALDO da Messi mole leekan sii, o tun gba World Footballer of the Year

RONALDO tun ti da Messi mole leekan si, oun tun ni World Footballer of the Year!
Aramanda agbaboolu fun Real Madrid ati Portugal, Christiene Ronaldo, tun ti foju Messi gbole leekan si o.
Oun ni won tun sese yan ni World Footballer of the Year, ninu asekaga nla to sese waye.
O gba ami eye naa mo Messi, Neymar ati awon to ku lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù

Nítorí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀, àwọn aláṣẹ Fásitì KWASU lé olùkọ́ kan dànù Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn …