St Janet gbe awon ota re s’epe
Oludasile ati pasto ni St Janet Cathedral, iyen olorin alufaasa ti a mo si St Janet, ti fi epe ragudu kan ranse si awon ota ile at iota ode re.
Ninu atejade kan to gbe sori ero alatagba, o ni, “Gbogbo eda to n reti eleya mi yoo sunkun kikoro”
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…