Gbogbo Yorùbá gbọdọ̀ gbárùkù ti Gani Adams lẹ́yìn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ tunun – Ayọ Debanjo
Agba oselu, Oloye Ayo Adebanjo, ti fi idunnu re han lori bi Alaafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, se fi Otunba Gani Adams je oye Aare Ona Kakanfo tuntun.
Adebanjo ni ojulowo omo Yoruba ni Gani Adams, to si ti ja fun ilosiwaju re.
O ni asiko ti iwosi n gun ile Yoruba yii gan-an ni a nilo Aaare Ona Kakanfo bii ti Gani.
O wa ro retu-t0mo pe ki won se atileyin gidi fun un.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…