Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfo: Ẹ̀rù ń ba Femi Okurounmu
Okan lara awon ogoa Afenifere, OloyeFemi Okurounmu, ti kominu lori bi Otunba Gani Adams se fe teri gba oye Aare Ona Kakanfo Yoruba.
Eru to n ba baba naa ni pe awon to ti je oye naa seyin saaba maa n bo sinu wahala to maa n mu emi won lo.
Okurounmu ni ojo ori Gani Adams si kere, to si je pe ise lo ye ki Alaafin wa eni to dagba ju u lo, to ti ta, to si ti ra, to si ti se aseyori nla fun ile Yoruba.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…