Home LÁGBO ÀRÍYÁ Idi ti mo fi n se Business Administration ni UNILAG – Odunlade Adekola
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 10, 2017

Idi ti mo fi n se Business Administration ni UNILAG – Odunlade Adekola

 

 

Laipe yii ni awon ololufe osere fiimu pataki, iyen Odunlade Adekola, yoo ba a je iresi, nigba ti o ba fe se ayeye ikekoo-jade ni University of Lagos.

Eko Business Administration, ti awon omo ile iwe maa n pe ni Bus Admin, ni o n se nibe, to si je pe odun karun-un , 500 Level lo wa.

O so fun awon oniroyin pe oun ti ni Diploma tele ni Moshood Abiola Polytechnic ni Abeokuta.

O ni idi ti oun fi yan Business Admin laayo ni pe o je ilana eko kan too wulo fun gbogbo eniyan. O ni bi eniyan lowo, o gbodo mo ona lati de e mole; bi eniyan nile ise, o gbodo ni imo Business Admin, to fi mo dokita to wa ni osibitu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…