Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Ahmed Musa si petrol station miran si Kano
ERÉ ÌDÁRAYÁ - October 10, 2017

Ahmed Musa si petrol station miran si Kano

 

Awon agbaboolu ode oni ti gbon gidi gan-an o, won ko na owo won ni ina-kunaa bi awon akegbe won tigba kan.

Bi won se n se fun ebi ati ara won ni won n de owo won mole, nipa sise ise okowo lorisiirisii.

Okan lara won ni Ahmed Musa.

IROYIN OWURO gbo pe o sese si ile ise ti won ti n ta epo, iyen petrol station miran si Kano.

Laipe yii lo si gbagede ere idaraya kan si ilu naa, ti owo re to eedegberun milionu naira (N500m).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…