Ọlọ́run rọ̀jò ẹja sí Israel
Bi o se wu Eledua lo n sola re, ko si eni ti o maa bii, kabiyesi re o Oba ogo. Dipo omi lasan to maa n ro ni opo ilu, eja ni Olodumare ro si orileede yii.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…