Bolatito: Aye n duro de iyawo Ooni tuntun
Opo eniyan lo ti n soju fetofeto bayii, lati ri eni ti yoo je iyawo Ooni ti Ife tuntun, leyin ti olori tele gba ona tie lo.
Awon kan ni Bolatito ni oruko ‘lucky babe’ tuntun n je, to si je pe o dara bi egbin, to si niwa tutu bi adaba.
Iroyin kan so pe laipe yii, lasiko Odun Olojo, ni Ooni yoo fi oju olori tuntun naa han aye.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…