Eyiara: Yemi Aalde fi rin-n-gi simu!
Laye ti okunrin n fi rin-n-gi s’eti nitori oge yii, ko si ohun ti awon gbajumo ko ni se tan.
Yemi Alade naa ti se kasiara bayii nipa pe o ti lu imu re to si gbe rin-n-gi kan to n tan yinrinyinrin si i.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…