Home iroyin Buhari fẹjọ́ àwọn adàlúrú sun àgbáyé
iroyin - September 19, 2017

Buhari fẹjọ́ àwọn adàlúrú sun àgbáyé

Nibi ipade eleekejilelaadorin to n lo lowo ni ilu New York lorileede Amerika ni Aare Muhammadu Buhari ti Naijiria ti lo fejo awon adaluru bii Boko Haram ati awon akegbe won sun ajo agbalaaye.

O ni gbogbo ohun to ba gba ni ki ajo agbaaye je ki awon fun awon ajo buruku to n da aye laamu. Lara awon ti Aare Buhari fejo won sun ajo yii ni orileede North korea. O ni inu oun ko ba dun ti ajo naa ba le te siwaju ninu igbogun ti awon alaropin esin, asa tabi eya kaakiri agbaye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…