Ti mo ba t’aye wa, iwo naa ni maa fi se’yawo – Femi Adebayo so fun Omotayo
Osere fiimu, Femi Adebayo, ti so fun iyawo re, Omotayo Adebayo, pe bi oun ba pada waye leemewa, obinrin naa ni oun yoo fi se aya o.
Ife obinrin naa ti de Femi mole, to si n pa a bi oti.
Lasiko ti o n ki arabinrin naa ku oriire ojo ibi re, Femi ni o ti mu idunnu ati ayo wonu aye oun.
Idi niyi to fi n ki i ni ‘Aduke’ mesan-an, mewaa.
O ni o sese wa ye oun wi pe suuru ti oun ni ki oun to se alabapade Omotayo ko ja s’ofo.
Osere fiimu naa ti koko ni iyawo kan tele, ti igbeyawo naa si f’ori sanpon.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…