Àarẹ Buhari tẹkọ̀ létí lọ New York
Aare Mohammadu Buhari te oko leti lo si New York ni oni fun ipade to maa bere ni ojo Aje, ojo kerindinlogun osu yii. Ipade naa ni o maa je eleekejilelaadorin iru re lati igba ti won ti da ajo naa sile.
Ipade UNGA (United Nations General Assembly) wa fun olori orileede kookan. Awon olori orileede ti ko din ni metalelaadorun-un ni o maa peju si ibi ipade naa. Ibe ni onikaluku ti maa salaye awon isoro to n koju orileede re.
Yato si awon gomina, awon minisita meje lo tun tele Aare lo si ilu New York ni orileede Amerika.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…