Home LÁGBO ÀRÍYÁ Won ni won ri oruka igbeyawo lowo Genevieve
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 16, 2017

Won ni won ri oruka igbeyawo lowo Genevieve

Fetofeto ni awon olofofo n wo owo osere fiimu ti a mo si Genevieve Nnaji bayii o.

Arabinrin naa tip e omo odun mejidinlogoji, sugbon to tii loko.

O ni omobinrin kan ti oun naa ti n dagba, sugbon oun ati baba omo naa ko fe ara won.

Lasiko kan, o dabi eni pe akorin D;Banj fe fe e niyawo, sugbon eleyii ko ri bee nigbeyin. D;Banj naa ti se igbeyawo bayii.

Lodun to lo bakan naa, won ni o seese ki Gnevieve ati okunrin kan to je agbaboolu alafowoogba, Ugochukwu Udezue, fe ara won. Eyi naa ko ri bee.

Sugbon lojo Jimoo, Gnevieve gbe foto kan jade ti oruka kan n yoju ni owo re. Eyi lo fa a ti gbogbo eniyan fi n ro pe boya oro ti ri bee ni.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…