Home Orisirisi O jigbijigbi! Idije kissing laarin Pastor Adeboye, Tinubu, Ajimobi, Wike, Oshiomhole ati Uduaghan!
Orisirisi - September 16, 2017

O jigbijigbi! Idije kissing laarin Pastor Adeboye, Tinubu, Ajimobi, Wike, Oshiomhole ati Uduaghan!

Ta lo mo kinni ohun se jura won lo?

To ba di oro gbigbe enu si ara eni lenu ni ilana ti ololufe, opo loko-laya ni ko le fi sere. Koda, awon eniyan ti e ko lero pe won le kiisi ni ita gbangba le deede sei, o ti sele si awon eni nla bii marun-un, to si je pe Oludari Agba Lagbaaye fun Ijo Redeemed Christian Church of God, Pastor E. A. Adeboye  ati iyawo re, Pastor Foluke Adeboye, wa lara won.

Awon eni oro tun kan ni Asiwaju Bola Tinubu ati iyawo re, Remi;  Gomina Oyo, Senitor Isiaka Ajimobi ati iyawo re, Florence ; Gomina Ipinle Edo tele, Comrade Adams Oshiomhole ati aya re, Iara; Gomina Ipinle Rivers, Alagba Nyesom Wike ati iyawo re,  Suzette; pelu Gomina Ipinle Delta tele, Uduaghan ati aya re, Roli. Aare ana, Goodluck Jonathan, ati iyawo re, Patience Mama Peace, naa ko so pe awon ko si nibe.

IROYIN OWURO gbe aworan awon ‘kissing’ nla nla yii jade. Ibeere wa nip e: Ta lo moo kiisi ju laarin awon eniyan yii?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…