Babalawo ni gbogbo awon omo mi – Wande Abimbola
. O tun ni iyawo oun to je oyinbo mo Ifa pupo
Oga Agba (Vice Chancellor) ni Obafemi Awolowo University, Ile-Ife, tele, Ojogbon Wande Abimbola, ti salaye pe babalaw ni gbogbo awon idile oun.
O ni Olorun yonda opolopo omo fun oun to si je pe babalawo ni gbogbo won.
O ni okan lara awon iyawo oun to je oyinbo naa mo Ifa debi pe Iyanifa ni, to si maa n difa, to si n sun iyere.
Abimbola so eyi di mimo ninu iforowanilenuwo kan pelu awon oniroyin.
O ni esin ibile ati asa Yoruba se pataki, to si le tan opo isoro ti a ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…