Alainilaari ni okunrin ti mo fe – Bimbo Akinsanya
Osere fiimu Yoruba ti a mo si Bimbo Akinsanya ti so pe alainilaari eniyan ni okunrin ti oun ba se mareeji tele.
O ni leyin pe o maa n lu oun ni ilu baara, o tun je alagbere ti ko legbe.
Bunmi Akinsanya ni wahala ti oun koju ninu igbeyawo naa le debi pe omo oun ko tii ju osu meta lo ti oun ti kuro nile okunrin naa.
Odun 2015 ni osere fiimu naa se igbeyawo
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…