Sooso meji: Minisita to fe dibo fun Atiku foju rinju pelu Buhari
Olorun lo mo ohun ti yo maa lo lokan Aare Muhammadu Buhari ati Minisita fun oro awon Obinrin, Iyaafin Aisha Alhassan, lonii, nigba ti won se ipade Igbimo ni Abuja.
Bi o tile je pe minisita ni labe Buhari, obinrin naa ti so pe ni 2019, Atiku Abubakar ni oun yoo dibo fun, tori oun ni baba nigbejo oun.
Akoko niyi ti Buhari ati minisita naa yoo foju rinju, tori oro ti won kii se sooso meji ti ko gbodo foju rinju.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…