E get as e be: Oga agba nile ise ijoba Ipinle Eko p’okunso ni Abeokuta!
Oga agba kan ni ile ise ijoba ni Ipinle Eko, ni abala Ministry of Youths and Sports, Ogbeni Oludare Buraimoh, ti pokunso.
Okunrin naa pokunso ni ile re to wa ni Abeokuta ni irole ojo Monday, lona to n se opo eniyan ni kayefi.
Omo re ti oruko re n je Dotun lo so eyi di mimo.
Inu ibanuje ni iyawo oloogbe naa wa.
O ni oun ko mo ohun to le fa a ti baale oun yoo fi pokunso. O ni teletele, nnkan le fun awon, sugbon bayii, nnkan ti de awon lorun, ki Buraimoh to wa pa ara re
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…