Home iroyin Awon ti Ajimobi sese fi je oba n’Ibadan kan n ba kadara ja ni – Olubadan
iroyin - September 13, 2017

Awon ti Ajimobi sese fi je oba n’Ibadan kan n ba kadara ja ni – Olubadan

Olubadan ti Ibadan, Oba Saliu Adetunji, tun ti fi ilodisi re han lori bi ijoba Abiola Ajimobi se yan oba mokanlelogun miiran fun ilu nla naa o.

Kabiyesi ni oro oba jije kii se ohun ti a maa n dogbon si.

O ni kikan lo maa n kan, eni kan kii bimo ko so o ni baale. O ni ohun to leto ni, ti eniyan si gbodo maa duro de igba to ba kan an.

Kabiyesi ni ogoji odun gbako ni oun fi wa ninu eto oye Ibadan, to si je pe lati igba naa ni oun ti je oye Mogaji idile oun.

O wa fi kun un pe ade to wa lori awon oba tuntun naa, ade yebuyebu, ade paali lasan ni.

Olubadan so eyi lasiko ti awon Mogaji se abewo si i ni aafin re lojo Isegun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…