Home iroyin Soyinka tún fẹnu sí àtúntò Naijiria
iroyin - September 12, 2017

Soyinka tún fẹnu sí àtúntò Naijiria

Ojogbon Wole Soyinka ma tun ti fenu si atunto Naijiria ni ana ni ibi to ti n ba awon oniroyin soro l”Eko, nibi ipade awon onkowe mewaa ti won we yan kanin-kanin lati lo si orileede Labanon.

Soyinka ni o tile ti fee pe ju lati jokoo atunto orileede yii. O ni gbogbo awon ti won ba n gbimo po lodi si atunto orileede yii ko fe ile yi fe ire. Iru won si tun kundun iyanje. O ni ti a ko ba fe ki awon kan maa sise fun awon kan je, o ye ki a se atunto orileede yii.

Ojogbon yii tun fenu sii pe oun  tun fara mo olopaa ipinle fun eto aabo to muna doko. O ni eyi maa le je ki ipinle kookan foju to ipinle re.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…