Owo olopaa te omobinrin to fe seku pa Okey Bakassi
Owo awon olopaa ti te omobinrin kan to ti n yo okunrin alawada stand up comedy, Okey Bakassi, lenu fungba die.
Okey Bakassi ni omobinrin naa ti n ran ise iku si oun, to si ni oun yoo ji anti oun gbe lo.
Okey Bakassi dupe pupo lowo olu ile ise olopaa. O si so pe oun ko mo ohun ti oun fi se obinrin naa.
Gege bi o ti so, o ni omo naa ti n bebe lodo awon agbofinro bayii, to si so pe esu laalu onile orita lo n ti oun ni itikuti.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…