Home LÁGBO ÀRÍYÁ Oro iya lara omo: Remi Surutu ranti omo re to salaisi loni ojo ibi re
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 12, 2017

Oro iya lara omo: Remi Surutu ranti omo re to salaisi loni ojo ibi re

Ti ko ba je pe iku se abosi ni, akobi Remi Surutu, Ayomide, ko ba se ojo ibi odun ketalelogbon re lonii. Sugbon iku bola je ni ose die seyin.

Sibesibe, Surutu seranti omo naa, to si ki i ni mesan-an mewaa.

Koda, o ba a soro bi eni pe o si wa laaye ni.

O ni omo naa je eni ti o lakikanju, o gbiyanju pupo lati koju isoso aromoleegun to mu u.

O ni o si je omo to gboro si obi lenu, to si ni erin ife lenu.

Ki Olorun fori jin omo naa, ko si fi iya re lokan bale.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…