O ga ju Akeredolu ati Osinbajo se SWAGGER!
Gomina Ipinle Ondo, Arakunrin Rotimi Akeredolu ati Igbakeji Aare Orile-Ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo, fihan pe ko si arugbo ni Ghana lonii, ni iluAkure.
Eyin e wo bi won se ki ara won ninu foto yii, nigba ti Osinbajo wo ilu Akure fun ipade awon National Council on Niger Delta…
SWAGGER naa ga ju!
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…