Home iroyin Customs gbẹ́sẹ̀ lé ìbọn ìjagun 1,100
iroyin - September 12, 2017

Customs gbẹ́sẹ̀ lé ìbọn ìjagun 1,100

Awon eso asobode ile wa ni won ti gba ibon eedegbefa ti won se daruke re wo orileede yii ni agbegbe Tin-Can Island l’Eko lati orileede Turkey.

Oga awon eso oju ona naa, Hameed Ali ni eleeketa niyi laarin osu mejo ti awon maa gba ibon ijagun ti ko niye lowo awon onidaruke yii.

Gbogbo awon ibeere to tun ro mo bi idi ti awon ibon yii fi n wole, ohun ti won fe fi awon ibon naa se ati awon ibeere miran ni a ko ri eni to maa dahun re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…