Afaimo ni ki Dekunle Gold ati Simi ma di tokotiyawo
Oro ife ti won lo wa laarin Adekunle Gold ati Simi ti fe di nnkan miiran bayii o, bi a ba wo owo ti iya Dekunle Gold fi mu omobinrin naa.
O jo pe iya naa fe ki omo oun so Simi di aya.
Lasiko ti Simi n se akanse ere ti won n pe ni concert, iya re ati iya Dekunle Gold wa nibe, leyii to dab ii pea won ana ti n se ana funra won.
Ninu iforowanilenuwo kan nibe, iya Dekunle ni omo daadaa ni Simi. O ni o ni iwa irele, to si je alakikanju omo.
Kin lo tun wa ku leyin eyi? O jo pe afaimo ni ki awon omo mejeeji ma di toko-tiyawo.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…