Home iroyin Ó se, àwọn ajínigbé jí olólùfẹ́ méjì gbé lọ lọ́jọ́ tí wọ́n fẹ́ ṣe engagement
iroyin - September 11, 2017

Ó se, àwọn ajínigbé jí olólùfẹ́ méjì gbé lọ lọ́jọ́ tí wọ́n fẹ́ ṣe engagement

Awon ajinigbe ti a mo si kidnapper tun dan ara miiran lojo Sunday o, nigba ti won ji ololufe meji ati ebi won gbe lo lojo ti won fe lo se abala igbeyawo ti awon oloyinbo n pe ni engagement.
Akunnu Akoko ni a gbo pe isele laabi naa gbe sele ni Ipinle Ondo.
Oruko okunrin naa ni Moses Yakubu, nigba ti a ko tii mo oruko iyawo ati awon molebi won ti won gbe lo.
Iroyin fi ye wa pe lati Ipinle Kogi ni tokotaya lola ti n bo, ti awon karanbaani naa fid a won duro, ti won si dari won sinu igbo.
A gbo pe won ti fi iyawo sile, sugbon Moses si wa pelu won.
Awon olopaa ipinle naa ni awon ti bere ise lori ati je ki Moses ati awon eniyan re to ku di itusile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…