Home iroyin Ní ìpínlẹ̀ Ògùn, Abéégúndé fipá bá ọmọ ọdún méje lòpọ̀
iroyin - September 11, 2017

Ní ìpínlẹ̀ Ògùn, Abéégúndé fipá bá ọmọ ọdún méje lòpọ̀

Inu ibanuje nla ni awon obi omo odun meje kan ni ilu Ota, Ipinle Ogun, wa bayii o, tori okunrin oran-ma-sunwon kan ti se isekuse pelu omo naa.
Okunrin ti won pe oruko re ni Ezekiel Abegunde lo ba omo naa sun, leyii to ti di wahala gidi.
Omo ogoji odun ni won pe okunrin ohun.
Iya omo naa ti mu ejo lo si odo awon olopaa, ti won si ti gbe oloriboobo naa ju si atimole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega

Ẹ dá Nàìjíríà padà sí ìpínlẹ̀ méjìlá tàbí ẹkùn mẹ́fà-Jega Ọrẹ Òtítọ́jù “Ó dìgbà tí a bá dà…