Home LÁGBO ÀRÍYÁ E ma fi kun ojo ori mi, n ko tii pe ogoji odun o – Eniola Badmus
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 9, 2017

E ma fi kun ojo ori mi, n ko tii pe ogoji odun o – Eniola Badmus

Elere fiimu, Eniola Badmus,  ti so pe omo odun merinlelogbon (34 years) pere lohun o.

O ni iro ni awon ti won so pe oun ti di eni ogoji odun.

Eniola Badmus sese se ayeye ojo ibi re ni, to si gbe awon foto kan to le koko sita, bii awon ti a se afihan re yii.

Awon agba oje onifoto, ORACLE PHOTOS, lo ya akoko nibe.

Pelu bi Eniola se so pe oun sese peomo 34 ni, o tumo si pe ore re Funke Akindele fi odun mefa ju u lo, ti Opeyemi Ayeola naa si fi iye odun naa ju u lo, tori awon mejeeji sese se ayeye ogoji odun won ni.

Boya aunti lo tie ye ki Eniola Badmus maa pe won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…