Abiara feyin ti ni CAC, Oladeji ni adari ijo bayii
Leyin opolopo odun ti Pstor S. K. Abiara ti je Adari Ijo Christ Apostolic Church, baba naa ti feyinti bayii.
Idi ni pe o ti pe eni odun marunlelaadorin – 75 years.
Adari tuntun fun ijo naa ni Eniowo Hezekiah Oladeji, to je adari CAC ni Canaanland, Ipinle Ogun tele.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…