Home Orisirisi Ojowu okunrin gun iyawo re lobe pa!
Orisirisi - September 7, 2017

Ojowu okunrin gun iyawo re lobe pa!

 

Esu laalu onile orita ti segun ninu aye okunrin kan ti oruko re n je Stephen Ogho-Oghene, latari bi o se gun iyawo re, Onyinye Faustina Eze, ni obe pa.

Aipe yii naa ni won se igbeyawo ni Ipinle Bayelsa, ti won n fi oruka sira won lowo, ti won si n je ete ara won pelu ife.

Okunrin naa ni oun kefin pe iyawo oun n se agbere, tori oun ri awon nnkan kan ninu foonu re, ni oun se pa a.

Odo awon olopaa lo ti n to boroboro bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…