Home Orisirisi E gba ni e laja, e waye obinrin ti ko ge eekanna re fun odun metalelogun (23 years)!
Orisirisi - September 7, 2017

E gba ni e laja, e waye obinrin ti ko ge eekanna re fun odun metalelogun (23 years)!

Bawo ni yoo ti ri ti eni kan ba fi eekanna sile fun odunmetalelogun (23 years) ti go ge e?

E ma wule tii laagun jinna! Obinrin kan ti se bee ni orile-ede Amerika, ni ilu Houston. Oun naa ni Ayanna Williams. Nigba ti o si ti se ohun ti eni kan ko se ri, o ti je ki oju araye ri ohun ti eni kan ko ri ri.

Bayii, eekanna re lo gun ju, debi pe won ti gbe ife eye Guinness Book of Records fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…